Isaiah 65:1

Ìdájọ́ àti ìgbàlà

1 a“Èmi fi ara mi hàn fún àwọn tí kò béèrè fún mi;
Àwọn tí kò wá mi ni wọ́n rí mi.
Sí àwọn orílẹ̀-èdè tí kò pe orúkọ mi,
Ni èmi wí pé, ‘Èmi nìyìí, Èmi nìyìí.’
Copyright information for YorBMYO